YBH 217

O HA le je p’ a mi

1. O HA le je p’ a mi?
Olugbala ha yan mi?
Bi ebi mi tip o to
O ha da oruko mi?
Olor’ elese ni mi
Mo ha je n’ ireti be?

2. A ha pe mi? O ya mi,
Nko gbodo se alaigbo;
Mo wole ni ese Re,
Mo sunmo ite anu:
Tire nikan ni mo nse,
Oluwa, ngo se ‘fe Re.

3. Mo ha ns’ omo Olorun.
Enit’ a ti f’ eje we;
Baba, f’ owo Re fa mi,
To mi de ‘le rere ni;
Nibit’ okan mi yio sun
L’ aiya Olugbala mi.

(Visited 128 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you