1. WO ti ngb’ adura igbagbo,
O ki ogb’ okan lowo ‘ku
T’ o gb’ ara re le O?
Emi ko l’ abo fun ‘ra mi,
Mo sad’ ohun ti Jesu se,
Nipa ‘jiya fun mi.
2. Enit’a pa fun elese,
Ododo Re pipe, ati
Eje Re, l’ebe mi;
Ododo ni y’o j’aso mi,
Pipe Re y’o dip’ese mi,
Yio sun mi m’Olorun.
3. Gba mi lowo ‘ku ailopin,
K’O mi emi isodomo,
Si ran itunu Re,
Nipa Re so oro iye;
Si so jeje fun okan mi,
P’, “Ore re l’Oluwa.”
(Visited 270 times, 1 visits today)