YBH 220

BABA, mo n’ owo mi si O

1. BABA, mo n’ owo mi si O;
Nko mo ‘ranwo miran:
Bi O ba kuro lodo mi,
A! nibo ni ngo lo?

2. Ohun t’ OmoRe f’ ara da
Ki nto la ‘ju s’ aiye!
Ise t’ O se lati gba mi
Lowo ‘ku ailopin!

3. Orisun ‘gbagbo, si O ni
Mo gb’ oju are mi:
Mba je le ri ebun ni gba
Laisi re mo segbe.

(Visited 336 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you