1. JESU, Ore ‘lese ni O;
B’ elese, mo now O;
Lat’ inu ekun ife Re,
Oluwa, ranti mi.
2. Se ‘ranti oro anu Re,
K’ Oranti Kalfari,
Ranti irora iku Re,
Ki O sir anti mi.
3. Alagbawi lodo Baba!
Mo f’ ara mi fun O;
B’ O ti joko lor’ ite Re,
Oluwa, ranti mi.
4. Loto mo jebi; mo s’ aimo,
Ofe n’igbala Re;
Nje ninu opo anu Re,
Oluwa, ranti mi.
5. Gbat’ iku ba p’oju mi de,
T’iranwo aiye lo,
Gbana, Olugbala owon,
K’Ojowo, ranti mi.
(Visited 389 times, 1 visits today)