YBH 228

NIHINYI n’ isimi gbe wa

1. NIHINYI n’ isimi gbe wa,
N’iha Re t’ eje nsan;
Eyi nikan n’ ireti mi,
Pe Jesu ku fun mi.

2. Olugbala, Olorun mi,
Orison f’ ese mi;
Ma f’ eje Re won mi titi,
K’ emi le di mimo.

3. We mi, si se mi ni Tire,
We mi, si je t’ emi;
We mi ki s’ ese mi nikan,
Owo at’ okan mi.

4. Ma sise l’ okan mi, Jesu,
Tit’ igbagbo y’o pin;
Tit’ ireti y’o fi d’ opin,
T’ okan mi y’o simi

(Visited 253 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you