YBH 230

TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re

1. TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re,
O nso ife Re si mi:
Sugbon mo fen de l’ apa igbagbo,
Ki nle tubo sunmo O.
Fa mi mora, mora, Oluwa,
Sib’ agbelebu t’ O ku,
Fa mi mora, mora, mora, Oluwa,
Sib’ eje Re t’ o n’ iye.

2. Ya mi si mimo fun ise Tire,
Nipa ore-ofe Re:
Je ki nfi okan igbagbo w’ oke,
K’ ife mi te si Tire.

3. A! ayo mimo ti wakati kan
Ti mo lo nib’ ite Re;
‘Gba mo gb’ adura si Olorun mi,
Mo ba soro bi ore.

4. Ijinle ife mbe ti nko le mo,
Titi ngo koja odo;
Ayo giga tie mi ko le so,
Titi ngo fi wa ‘simi.

(Visited 3,304 times, 6 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you