YBH 24

GBAT’ okan are fe ‘simi

1. GBAT’ okan are fe ‘simi,
T’ o nwa Olorun re,
B’ o ti dun to lati r’ ale
T’ o pin ose lala.

2. Adun lati r’ oye ‘mole
T’ o la si oju wa,
Nigba oro isokanji
Tan imole titun.

3. ugbon wakati re nsare;
Ki o to de opin,
Emi Mimo masai fun mi
N’ isimi l’ okan mi.

(Visited 302 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you