YBH 240

Ko s’ ona si ayo orun

1. Ko s’ ona si ayo orun,
S’ ayo at’ alafia toto,
Lehin Jesu, Ona;
Jek’ a rin l’ ona mimo na,
K’ a f’ igbagbo ko ‘rin titi;
Ao fi ba A joko.

2. B’ ife Jesu ti ga to!
O ga ju orun loke,
O jin ju ile okun,
O to bi aiyeraiye;
Ife t’ o wa mi kiri,
Ri mi nigbati nko wa.

3. Ogbo elese ni mi;
Sugbon Jesu to fun mi:
Gbogbo aini mi l’ O mo,
Gbogbo edun mi, Tire;
Lodo Re ko s’ iberu,
On l’ o se emi mi ro.

(Visited 355 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you