YBH 241

OLUWA ib’ isadi mi

1. OLUWA ib’ isadi mi,
‘Wo ni mo gbekele;
Oro Re gba mi n’ iyanju,
Emi erupe ‘le.

2. Awiye ko si l’ enu mi,
Ko si ebe miran;
O to pe Olugbala ku,
O ku lati gba mi.

3. Gba iji idanwo ba nja,
T’ ota d’ oju ko mi,
Ite anu li abo mi,
Reti mi wa loke.

4. Kuro ninu ija ahon,
Okan mi fo si O;
Ero yi mu okan mi yo
Pe, “Jesu ku fun mi.”

(Visited 387 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you