YBH 26

JI, enyin mimo ji

1. JI, enyin mimo ji,
E k’ ojo owo yi,
E fi orin iyin
At’ ayo juba Re;
Wa bukun ojo t’ a bukun
Eya isimi ti orun.

2. Ni oro rere yi
L’ Oluwa ji dide,
O fo ‘lekun iku,
O segun ota wa;
O si ngb’ ejo war o loke,
O nkore eso ife Re.

3. Kabiyesi, Oba!
Hosanna ndun loke;
Aiye l’ ohun ‘rele
Si ngba iyin Re ko;
Yiye l’ Od-agutan t’ a pa,
Lati wa, lat6i joba lai.

(Visited 473 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you