YBH 269

OKAN mi, Oluwa ni

1. OKAN mi, Oluwa ni,
Jesu re ni, gb’ oro Re;
Jesu nso, O mba o so,
Pe, “Elese, ‘wo fe mi?”

2. ‘Gbat’ a de o, mo da o,
O gb’ ogbe, mo wo o san;
‘Gb’ sako, mo mu o bo;
Mo s’ okun re d’ imole.

3. Kike iya ha le mo
Si omo re ti o bi?
Lotito, o le gbagbe,
Sugbon Em’ o ranti re.

4. Ife t’emi ki ye lai,
O ga rekoja orun,
O si jin ju okun lo,
Ife alailegbe ni.

5. ‘Wo fere r’ ogo Mi na,
‘Gb’ ise ore-ofe tan;
‘Wo o ba Mi gunwa po,
Wi, “Elese, ‘wo fe mi?”

6. Olori aroye mi,
Ni pe ife mi tutu;
Sugbon mo fe O, Jesu,
A! mba le fe O ju yi!

(Visited 560 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you