1. EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de,
Lati mu mi lo si ile Re orun,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Refrain
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
2. Emi ko mo orin t’ angeli nko,
Emi ko si mo iro duru won,
Sugbon mo mo pea o d’ oruko Jesu,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Refrain
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
3. Emi ko mo b’ ile m’ orun ti ri,
Ati oruko tin go je nibe,
Sugbon mo mo pe Jesu yio pe mi wo ‘le,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Refrain
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
(Visited 577 times, 1 visits today)