YBH 278

AYO omo anu ti to

1. AYO omo anu ti to!
T’ o mo idariji:
O nwip’ aiye ki se ‘le mi,
Mo nwa ‘le mi s’ orun

2. Ilu t’ o jin s’ oju eda,
Mo nfi ‘gbagbo ri i;
Ile ayo awon mimo,
Ti a pese fun mi.

3. Ireti nla kini ti wa
Nigbat’ a wa l’ aiye?
A ngb’ adun agbara orun,
A nkanju ojo na.

4. Ara nso p’ ajinde de tan,
Emi wa wa n’nu Kristi’;
Ara erupe wa si kun
Nihin fun ogo Re.

(Visited 448 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you