YBH 283

ALAFIA pel’ Oluwa

1. ALAFIA pel’ Oluwa,
A, ede wo l’ eyi!
A f’ eje b’ elese la ‘ja,
Oto ‘simi l’ eyi.

2. Ni iwa ati ni ise,
Mo jina s’ Olorun;
Sugbon ore-ofe fa mi,
Sunmo nipa ‘gbagbo.

3. Mo sunmo Q nisisiyi,
Nko le sunmo ju be,
Nitori nipa Omo Re,
Bi Re ni mo sunm’ O.

4. Owon li owo Olorun,
Nko le s’ owon ju be,
Ife t’ O ni si Omo Re
L’ O ni si mi pelu.

(Visited 251 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you