YBH 287

ISIN l’ o le fun wa li

1. ISIN l’ o le fun wa li
Ayo didun li aiye;
Isin ni yio fun wa li
Itunu nigba ba ku.

2. Lehin ‘ku ayo re y’o
Wa titi aiyeraiye;
Ki Olorun j’ ore mi,
Ayo mi ki y’o l’ opin.

(Visited 240 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you