YBH 289

OLORUN ‘yanu! Ona kan

1. OLORUN ‘yanu! Ona kan
Ti o dabi Tire ko si;
Gbogb’ ogo ore-ofe Re
L’ o farahan bi Olorun.
Tal’ Olorun ti dariji,
Ore tal’ o po bi Tire?

2. N’ iyanu at’ ayo l’ a gba
Idariji Olorun wa;
‘Dariji f’ ese t’ o tobi,
T’ a f’ eje Jesu s’ edidi.

3. Je ki ore-ofe Re yi,
Ife iyanu nla Re yi,
K’o f’ iyin kun gbogbo aiye,
Pelu egbe Angel’ l’ oke.

(Visited 364 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you