1. BO ti dun to l’ oj’ owo yi,
Ojo t’ o dara ju,
Ki a pa ‘ronu aiye
Ki a pa ‘ronu nkan t’ orun!
2. B’ o ti dun to lati l’ aye
Bebe fun ‘dariji!
K’ a fi igboya omo pe
“Baba ti mbe l’ orun
3. Lati gb’ or’ Alafia didun
Lat’ enu ranse Re;
Lati mu k’ a sokun ese,
K’ a ri ona orun.
4. B’ o ba si je pe o ti wa
Lati le ese lo,
Enit’ O now inu okan,
Y’o ran or-ofe wa.
5. Nje ma wole ojo owo,
Ojo t’ o dara ju,
T’ okan pe lati san eje
Im’ore fun orun.
(Visited 560 times, 1 visits today)