1. EYO, eyin mimo, e yin
Ibukun; anu, igbala,
Jesu oke nyin titi lai,
D’ oju ko agbara iji.
2. Abo lowolowo ni se,
Ife Re to b’ oke giga;
Apata li oruko Re,
T’ iji at’ igbi ko le mi.
3. Ki paro bi ohun gbogbo,
Ki gbagbe ba ti gbagbe Re;
Ife Re lailai bakanna,
Oro Re to b’ oruko Re.
(Visited 277 times, 1 visits today)