YBH 293

JESU Od’-agutan

1. JESU Od’-agutan,
‘Wo t’ O ta ‘je Re le,
Lati gba wa lowo ‘parun,
Gba iyin ailopin.

2. Si O, Om’-Olorun,
L’ awon mimo nkorin,
‘Wo t’ O ru eru wuwo wa,
Oba Alade wa.

3. Ore awon t’ o nu,
O wa ‘le lat’ orun,
Lati san ‘gbese fun okan
K’ O fin won se Tire.

4. ‘Wo ‘simi alare,
Si odo Re l’ a wa;
K’ a le r’ ibugbe wa n’nu Re,
Ile aiyeraiye.

(Visited 373 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you