YBH 306

IKOSE ti po to, t’ a nri

1. IKOSE ti po to, t’ a nri
Li ona wa s’ ite anu
Sibe, tani mo ‘yi adua
Ti ki y’o fe ma wa nibe.

2. Adua nit u ‘ju ojo ka,
Ni gun ategun Jakobu;
Adua l’ agbara igbagbo,
Ni mu ibukun sokale.

3. Adura mu ki ija tan,
A si ma fun ni l’ agbara,
Satani gbon nigbat’ o ri,
Elese lori ekun re.

4. O ko ha ri wi? Tun ‘nu ro;
Je ki oro k’ o tu jade,
Bi igbati o nro edun
Fun omo-enikeji re.

5. A! iba je p’ oke l’ o mi,
Idaji edun wonni si,
Se oro orin re ‘ba je,
“Gb’ ohun t’ Oluwa se fun mi.”

(Visited 401 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you