YBH 312

GBA alare nwa sinmi

1. GBA alare nwa sinmi,
Ti nwon w’odo Re;
Gba nwon ko ‘banuje won
Wa si ‘waju Re;
Gb’eni damu w’alafia
Nke p’oruko Re;
Gba t’elese nwa iye,
Kunle l’ese Re:
Oluwa f’ife gbo ‘gbe won,
Li orun ni ibugbe Re.

2. Gba t’eni aiye wa o,
T’o Gb’okan soke:
Gb’oninakuna pada
S;ile baba re;
Gb’agberega w’oju Re
Ti tuba fun ;
Gba t’elebi m’ebi re
Wa b’ite anu;
Oluwa f’ife gbo ‘gbe won
Li orun ni ibugbe Re.

3. Gba t’alejo ko r’ile,
N’ibi t’yo sun si;
Gba t’o tosi fe onje
T’o si nwa ore;
Gba ti awon oloko
Kunle f’adura
Gba t’awon jagubjagun,
Gb’okan won si O;
Oluwa f’ife gbo ‘gbe won
Li orun ni ibugbe Re.

4. Gba t’eni t’o nse lala,
N’nu ogunlogo;
Gba ti olus’agutan,
Nke pe Olorun
Gbati aiye yi bas u
Awon ojogbon;
T’nwon si nfe ayo orun
Nke p’Olubukun;
Oluwa f’ife gbo ‘gbe won
Li orun ni ibugbe Re.

5. Gba t’omode jojolo,
Odo omidan,
Gba ti arugbo kege,
W’oju rere Re;
Gba t’opo dorikodo
Pelu ‘banuje,
Gbati omo orukan
N’nikan daro;
Oluwa f’ife gbo ‘gbe won
Li orun ni ibugbe Re.

6. Gbat’araiye n’nu rora,
Mi imi edun,
Gba t’awon omo ‘gbekun,
Sokun kikoro;
Gbati ijo Re l’aiye,
Ba nwa isimi
T’o si ke p’oruko Re;
Wa, Jesu dahun;
Oluwa f’ife gbo ‘gbe won
Li orun ni ibugbe Re.

(Visited 406 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you