YBH 315

TIRE l’ awa Kristi

1. TIRE l’ awa Kristi,
Titi aiyeraiye,
A fe fi gbogbo okan wa
Fun O patapata.

2. Ao ro mo O sibe,
Pelu itara nla;
B’ opo nfa wa lodo Jesu,
Ma je kin won bori

3. Emi Re so wa po
Mo O, Olori wa;
Y’o se wa bi aworan Re
Y’o ko wa l’ ona Re.

4. Iku le y’ okan wa
Lara erupe yi;
Sugbon ‘fe y’o sun wa mo O
Ninu okun aiye.

5. Okan pelu Kristi,
Awa o se beru?
Ko le te ite Re s’ orun,
Lai ko wa lo sibe.

(Visited 448 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you