YBH 318

BUKUN ni fun ohun

1. BUKUN ni fun ohun,
T’ o de wa po n’nu ‘fe;
Idapo awon olufe,
Dabi ijo t’ orun.

2. Niwaju ‘te Baba,
Li awa ngbadura;
Okan n’ ireti at’ eru,
Ati ni itunu.

3. Awa mb’ ara wa pin
Ninu wahala wa;
Awa si mb’ ara wa sokun
Ninu ‘banuje wa.

4. Nigbat’ a ba pinya,
Inu wa a baje;
Sibe okan wa y’o j’ okan
N’ ireti ipade.

(Visited 1,486 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you