YBH 325

ABA le n’ igbagbo aye

1. ABA le n’ igbagbo aye,
B’ o ti wu k’ ota po;
Igbagbo ti ko je mira
Fun aini at’ os

2. Igbagbo ti ko je rahun,
Labe ibawi Re;
Sugbon ti nsimi l’ Olorun
Nigba ibanuje.

3. Igbagbo tin tan siwaju,
Gbat iji ‘ponju de;
Ti ko si je siyemeji,
N’nu wahala gbogbo.

4. Igbagbo ti ng’ ona toro,
Titi emi o pin;
Ti y’o si f’ imole orun
Tan akete iku.

5. Jesu f’ igbagbo yi fun wa
Nje, b’ o ti wu k’ o ri,
Lat’ aiye yi lo ngo l’ ayo,
Ilu orun rere.

(Visited 782 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you