YBH 327

ISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yi

1. ISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yi,
Emi o se kun, ‘gbat’ iyonu ba de;
Simi okan mi, eyikeyi t’ o de,
O dun ajo mi ku, o mu k’ ile ya.

2. Ko to fun mi kin ma simi nibi yi,
Ki nsi ma ko le ‘le mi ninu aiye yi;
Ongbe ilu t’ a ko f’ owo ko ngbe mi,
Mo nreti aiye tie se ko baje.

3. Egun esusu le ma hu yi mi ka,
Sugbon emi ko nig be ‘ra le aiye;
Emi ko wa isimi kan ni aiye,
Tit’, em’ o fi simi l’ aiya Jesu mi.

4. Jek’ idanwo at’ ewu wa l’ ona mi,
Nwon mu k’ orun tubo dun nigb’ aiye pin;
Ibanuje tab’ ohunkohun le de,
Wakati kan lodo Jesu to fun mi.

(Visited 998 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you