YBH 328

IGBA wa mbe li owo Re

1. IGBA wa mbe li owo Re,
A fe ko wa nibe;
A fie mi at’ ara wa
Si abe iso Re.

2. Igba wa mbe li owo Re,
Awa o se beru?
Baba ki y’o je k’ omo Re,
Sokun li ainidi.

3. Igba wa mbe li owo Re,
‘Wo l’ a o gbekele;
Tit’ a o f’ aiye osi ‘le
T’ a o si r’ ogo Re.

4. Igba wa mbe li owo Re
Ngo ma simi le O,
Lehin iku, low, otun Re.
L’ em o wa titi lai.

(Visited 2,464 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you