1. OLORUN Olodumare,
Alanu, Olore,
Iwo l’ O da gbogbo aiye,
Ati orun pelu.
2. Gbat’ O da Adam’, baba wa
S’ inu ogba Eden’,
Ko s’ ohun t’ o lalasi re,
O wa ni irora.
3. Sugbon nigbati o subu,
O pa ase Re da,
Pe, “Lati ogun oju re
N’yo r’onje onje ojo re.
4. Titi d’oni lie gun yi
Wa lor’awon ‘mo re,
Ti nwon nse lala f’onje won,
Lati gb’emi won ro.
5. Jesu f’ id’ ise, won mule,
Gba wa lowo ota,
Pese fun nwon nigbagbogbo,
Ki nwon le wa fun O.
(Visited 350 times, 1 visits today)