1. JI, okan mi, dide giri,
Ma lepa nso kikan;
F’ itara sure ije yi
F’ orun, f’ ade iye.
2. Awosanma eleri wa,
Ti nwon nf’ oju sun O;
Gbagbe irin at’ ehinwa,
Sa ma te siwaju.
3. Olorun nf’ ohun igbera
K si o lat oke:
Tikare l’ o npin ere na
T’ o nnoga lati wo.
4. Olugbala, ‘Wo l’ o mu mi
Bere ije mi yi;
Nigbat a ba de mi l’ ade,
Ngo wole l’ ese Re.
(Visited 441 times, 1 visits today)