YBH 340

OJISE Krist’, dide

1. OJISE Krist’, dide,
E mura fun ‘se na,
Iri ‘bukun lat’ orun wa
Ti se s’ ori ile.

2. Lo toju alaisan,
At’ awon ti nsofo,
Lo s’ odo awon ti nronu,
K’ o si tu won ninu.

3. F’ itara se ‘ranwo
Fun awon elese,
Nibit’ ijo mimo nkunle,
T’ olukoni pe si.

4. Fa ‘gbagbo ti nf’ oju
Adua w’ oke mora,
Si f’ ife ti ki yipada,
Ti Jesu bo ‘ra re.

5. Gbana ‘wo o pin n’nu
Oro ti ki baje,
‘Bukun t’ o wa n’nu ‘hinrere,
Yio san lala re.

(Visited 498 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you