YBH 341

KO mi, Oluwa mi

1. KO mi, Oluwa mi,
Ki nr’ owo Re yika,
Ki nsi ma se ohun gbogbo,
Bi enipe fun O.

2. Gbogbo aiye le se
Alabapin n’nu Re,
Ko si ise ti ko n’ iyi,
T’ a se nitori Re.

3. Itele ofin Re
Mu ‘se asan l’ ogo,
Ise n’ iyi, o’ n’ ibukun,
T’ o n’ iru ‘pile yi.

(Visited 327 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you