1. OG’ Oluwa j’ ohun ‘yanu,
Ona Re si yato;
Ko si j’ ohun t’ o wu eda,
Lati fi iyin fun.
2. Ibukun ni f’ awon t’ a fun
L’ oye lati mo pe,
Olorun wa pelu awon,
Bi nwon ko tile ri.
3. Ibukun ni f’ awon t’ o mo
‘Biti oto gbe wa,
Ti nwon si mu ipa rere,
T’ o wo l’ oju eda.
(Visited 359 times, 1 visits today)