YBH 343

SISE tori oru mbo ! Sise li owuro

1. SISE tori oru mbo ! Sise li owuro;
Sise nigba iri nse, sise n’nu ‘tanna;
Sise ki osan to pon, sise nigb’ orun nran,
Sise tori oru mbo ! ‘gb ise o pari.

2. Sise tori oru mbo ! Sise l’ osan gangan,
F’ akoko rere fun ‘se, isimi daju,
F’ olukuluku igba ni kan lati pamo;
Sise tori oru mbo ! ‘gb’ ise o pari.

3. Sise tori oru mbo ! Orun fere won a;
Sise gbat’ imole wa, ojo bu lo tan;
Sise titi de opin, sise titi ale,
Sise agbat’ ile ba nsu, gb’ ise o pari.

(Visited 1,993 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you