YBH 345

ARA mi fun ‘rugbin rere

1. ARA mi fun ‘rugbin rere,
Nigba ifunrugbin wa,
Ma sise l’ oruko Jesu,
Tit’ On o tun pada, wa,
Nigbana ni a o f’ayo ka a,
Olukore a ko won si aba.

2. Olugbala pase wipe,
” Sise nigbat’ o j’ osan
Oru mbowa,” mura giri,
Oloko fere de na,

3. T’ agba t’ ewe jumo ke pe,
‘Wo l’ oluranlowo wa;
Mu ni funrugbin igbagbo,
K’ a s’ eso itewogba,

4. Lala ise fere d’ opin,
Owo wa fe ba ere;
B’ O de ninu olanla Re,
Yio so fun w ape, “Siwo.”

(Visited 1,066 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you