1. ABE, a fe ri o,
Ojo ‘simi rere,
Gbogbo ose a ma wipe,
Iwo o ti pe to?
2. O ko w ape Kristi
Jinde ninu oku;
Gbogbo ose a ma wipe,
Iwo o ti pe to?
3. O so t’ ajinde wa
Gege bi ti Jesu;
Gbogbo ose a ma wipe,
Iwo o ti pe to?
4. Iwo so t’ isimi,
T’ ilu alafia;
T’ ibukun enia mimo,
Iwo o ti pe to?
(Visited 1,728 times, 9 visits today)