YBH 369

ENI ‘rele, t’ o nwa ‘gbala

1. ENI ‘rele, t’ o nwa ‘gbala
Nip’ eje Od’-agutan,
E gbo ohun isipaya,
Erin ‘na ti Jesu rin.s

2. Gbo Olugbala t’ O npe nyin,
F’ eti s’ ohun Re orun,
Ma beru ibi t’ o le de,
Nigbat’ e yan ona Re.

3. Jesu wipe, “Se ‘tebomi
Fun awon t’ o gba Mi gbo,”
A te On papa bo mi ri,
Ninu odo Jordan.

3. E to ipase Re nihin,
To lehin laiduro pe;
E fi ayo gba ase Re,
Wo! Olori nyin saju.

(Visited 347 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you