1. AM’Oluwa iye
Lo sinu ‘gbi mimo;
Enit’ O wa gb’ okan wa la
Ri l’ odo Jordani.
2. O f’ ona jeje han,
Ati ase mimo,
O ni k’ awon t’ a ra gboran,
Ki nwon to ‘pa ‘mole.
3. Ao gb’ ona ti O yan,
Olugbala mimo;
Jek’ ogo tan s’ or’ ase yi,
Rerin si wa loni.
(Visited 217 times, 1 visits today)