1. N’IFE l’ a te ona
T’ Olugbala ti rin;
A f’ apere Olori wa,
Agutan Olorun.
2. Li are Re nikan
N’ ireti war o mo,
Iwo t’ O s’ etutu f’ ese,
T’ O ku fun elese.
3. A gbekel’ ebo Re;
A sa b’ agbelebu;
A! k’ a ku s’ese, k’ a dide
Si iye ninu Re.
(Visited 328 times, 1 visits today)