1. L’ONA gbogbo t’ Oluwa yan,
Ajo mi l’ emi o to;
Ma da mi ro, eyin mimo,
Emi o ban yin lo.
2. Bi Jesu nlo ninu ina,
Emi o to lehin;
Ma da mi ro l’ emi o ke,
B’ aiye d’ oju ko mi.
3. Ninu isin at’ idanwo,
Em’ o lo l’ ase Re;
Ma da mi ro, emi o lo,
S’ ile Emammanuel’.
(Visited 298 times, 1 visits today)