1. EJERI, angel’ enia
Niwaju Oluwa,
On l’ awa mba da majemu,
T’ a ko gbodo baje.
2. Pe, tit’ aiye sf’ ara wa
Fun Krist’ Olugbala,
P’ a kio ye ninu ‘lana Re,
Tabi loju ija.
3. A ko gb’ ara le ipa wa,
Sugbon le ore Re;
Bi aini wa tin de, k’ O le
Ma pese iranwo.
4. To ese ‘sina wa s’ ona,
Mu war in l’ ona Re,
B’ a ti nso eje d’ adura,
Y’ adura wa s’ iyin.
(Visited 226 times, 1 visits today)