YBH 377

A BAPTIS’ wa sinu iku

1. A BAPTIS’ wa sinu iku,
Nipa itebo ‘mi;
A sin wa ‘nu ‘boji Jesu,
A sin wa pelu Re.

2. A ba Krist’ ku k’ a ba ye se,
K’ a le ji pelu Re,
K’ a le jere ebun titun
T’ y’o mu wa ye f’ oke.

3. Emi, fi ara Re fun wa;
K’ oro wa ko le je
Ireti Oluwa l’ oke,
At’ ifarahan Krist’.

4. Fun igbagbo wa li ogo,
Ayo ati ade,
Lat’ aiye k’ a le wa l’ oke
K’ a joko pelu Krist’.

(Visited 232 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you