1. AKO ha gb’ oro wuwo ni,
P’ a sin wa pelu Oluwa?
P’ a te wa ri sinu ‘ku Re,
A sib o ara osi ‘le.
2. Okan wa gba emi t’ orun,
A gbe kuro ninu iku;
Beni Krist’ jinde n’ iboji,
O si mb’ Olorun gbe l’ oke.
3. K’ a ma jek’ esu tun joba
Ninu ara iku wa mo,
Gbogbo ese ti a ti nda,
Ki yio j’ oba l’ ori wa mo.
(Visited 97 times, 1 visits today)