1. ONIGBAGBO, e wo
Oluwa nyin n’nu ‘se,
A ri s inu okun ‘rora,
T’ o b’ okan Re mo ‘le.
2. Nihin l’ a r’ iboji
T’ a sin Jesu wa si;
A fe k’ a ri wa sin’ odo,
Tor’ a ku pelu Re.
3. Nihin a ri O ji,
O wa, ko ni ku mo;
B’ okan pelu Re, a dide
Lati bag be l’ oke.
(Visited 209 times, 1 visits today)