1. BI a ti f’ okan wa fun O
Nip’ ase mimo Re,
Ran s’ or’ omi, ‘Daba orun,
F’ edidi t’ eje na.
2. Ogo fun-Eniti a pa
Nitor’ igbala wa,
T’ O ran wa lowo lati ja,
T’ O mu wa ye f’ orun.
3. L’ ayo a f’ aiye wa fun O,
Ati agbara wa,
Gba wa nin’ ase mimo yi,
Bukun akoko yi.
(Visited 131 times, 1 visits today)