1. DAB’ orun sokale,
Si fi ara Re han,
F’ife Oluwa han
F’ edidi Re di wa,
Laisi Re, asan n’ ise wa,
Ao si le ri itewogba.
2. Nigbati Jesu wa,
Om’ Alade ‘Mole!
Gba ase mimo yi,
N’nu odo Jordani;
A r’ aworan Re fo wa ‘le
B’ adaba o ba le lori.
3. Ma dan siwaju si
Da ‘na Re s’ inu wa,
Tire ni ase yi,
K’ O si ji okan wa;
‘Wo o toju awon ‘mo Re
Ileri Re wa titi lai.
(Visited 177 times, 1 visits today)