YBH 397

OKAN mi pe ninu Jesu

1. OKAN mi pe ninu Jesu:
Ko beru ise ofin mo;
Erin Olorun dun ninu,
Nibit’ o ti kun f’ ese ri.

2. Okan mi ye ninu Jesu;
O gb’ alafia ‘dariji Re;
Ogb’ ore-ofe iku Re,
O si nfi ijiya Re be.

3. Okan mi yio korin iyin,
S’ okan wa t’ O wa titi lai;
Yio sin n’ irele l’ ese Re,
‘Tori n’nu Re nikan l’ ope.

(Visited 241 times, 3 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you