YBH 399

ABBA, Baba,” a sunmo O

1. “ABBA, Baba,” a sunmo O
L’ oruko Jesu owon;
Aw’ omo Re t’ o pe nihin,
Nfe ‘bukun t’ O se ‘leri;
Eje Re we wa n’n ese wa,
Nipa Re l’ a sunmo O;
Emi Re pelu si ko wa
Lati ke, “Abba, Baba.”

2. Lekan bi oninokuno,
A ti sako lodo Re,
Sugbon or’ ofe Re t’o po
Si gba wa lowo ise;
A ti wow a l’ ewu ‘gbala,
Tabili Re n’ ipo wa;
Awa yo, ‘Wo si yo pelu,
Ninu oro ore Re.

(Visited 373 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you