YBH 403

KIL’ o le w’ ese mi nu

1. KIL’ o le w’ ese mi nu?
Ko si, lehin eje Jesu;
Kil’ o tun le wo mi san?
Ko si, lehin eje Jesu.
A! eje ‘yebiye,
T’ o mu mi fun bi sno,
Ko s’ isun miran mo,
Ko si lehin eje Jesu.

2. Fun ‘wenumo mi, nko ri,
Nkan mi, lehin eje Jesu;
Ohun ti mo gbekele
Fun ‘dariji, l’ eje Jesu.

3. Etutu f’ ese ko si,
Ko si lehin eje Jesu;
Ise rere kan ko si,
Ko si, lehin eje Jesu.

4. Gbogbo igbekele mi,
Ireti mi l’ eje Jesu;
Gbogbo ododo mi ni.

(Visited 2,006 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you