YBH 407

OLUWA wa mimo

1. OLUWA wa mimo,
Ti ogun orun nyin,
Masai gbo wa;
Kerubu, Serafu,
At’ awon angeli,
S’ odo R ni nwon nmu
Iyin nwon wa.

2. Fun oro Re n’ ipa,
Bukun ‘ranse Re yi;
Gba ise re;
Bi Jesu si ti nfi
Ami si oro re,
Ran Emi Re mimo,
Lati fi han.

3. B’ odun ti nrekoja,
Ki ayo ma po si
Ju t’ oni lo;
Yan kun ‘nu ile na
K’ aiye gba oto Re,
Oluwa wa.

(Visited 176 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you