YBH 408

JEK’ alore Sion dide

1. JEK’ alore Sion dide
Gba ipe fun ‘ra won;
Jeki nwon gba ase wuwo
Lat’ enu Oluwa.

2. Ki ‘se ise kekere ni
A nfe oluso si;
O to kun angeli l’ okan,
O kun Jesu lowo.

3. Nwon nso okan ti Oluwa
F’ ogo orun ‘le fun –
Okan ti yio wa titi lai,
N’nu ayo tab’ egbe.

4. K’ awon pa le ri Jesu na
Bi Olugbala won;
Si s’ okan won l’ ojojumo
Ki nwon le so fun O.

(Visited 203 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you