YBH 409

OLORUN ‘kore, te ‘ti Re

1. OLORUN ‘kore, te ‘ti Re,
F’ ara Re han l’ ogun Sion;
Ran ojise t’ o n’ itara,
T’ o yara lati gb’ ase Re.

2. Wo wa l’ oju Oluwa wa,
Ikore pon, o nre dede;
Ile nla si siwaju wa,
Ise po, osise kere.

3. Fi owo agbara Re to
Omo Sion nibi gbogbo,
Bi alore ‘gbala ofe,
Ki nwon bukun iran kiku.

(Visited 103 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you